quinta-feira, 18 de março de 2010

Òré nlá mi!

Mo fé imò fún orí ré

Kí gbogbo òrìsà kó ire tò é wá!

Ní ibodè yìí kò sí òsán, bèéni kò sí òru.

Kò sí òtútù, bèéni kò sí ooru.

Ohun àsírií kan kò sí ní ibodè yìí.

Ohun gbogbo dúró kedere nínu ìmólè olóòrun.

Àyànmó kò gbó oògùn.

Àkúnlèyàn òun ní àdáyébá.

Àdáyébá ni àdáyé se.

Kí òrìsà-nlá olú àtélesé, a gbénon dídùn là.